1 Thessalonians 1:2

Ọpẹ́ fún ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalonika

2 aGbogbo ìgbà ni a máa ń fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nítorí yín, a sì ń gbàdúrà fún un yín nígbà gbogbo pẹ̀lú.
Copyright information for YorBMYO